OMHBG

OMHBG

Ordinary Man Helped By God

  • Home
  • Featured
  • Contact
  • Disclaimer
  • Copyright
You are here: Home / Featured / Psalm 24 In Yoruba (Full Translation Language)

Psalm 24 In Yoruba (Full Translation Language)

May 5, 2023

Psalm 24 In Yoruba (Full Translation Language) :

Click Here To Listen To Over 429+ Apostle Joshua Selman Messages (Online Player) - 100% Free. Apostle Joshua Selman Messages
Psalm 24 In Yoruba

Psalm 24 In Yoruba

1 Ti Olúwa ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún rẹ̀,
ayé àti àwọn tí ó tẹ̀dó sínú rẹ̀;


CLICK HERE TO SUBMIT YOUR PRAYER REQUEST

2 Nítorí ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ lórí Òkun
ó sì gbé e kalẹ̀ lórí àwọn ìṣàn omi.

3 Ta ni yóò gun orí òkè Olúwa lọ?
Ta ni yóò dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀?

4 Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun,
ẹni tí kò gbé ọkàn rẹ̀ sókè sí asán
tí kò sì búra èké.

5 Òun ni yóò rí ìbùkún gbà láti ọ̀dọ̀ Olúwa,
àti òdodo lọ́wọ́ Ọlọ́run ìgbàlà rẹ̀.

6 Èyí ni ìran àwọn tí ń ṣe àfẹ́rí rẹ̀,
tí ń ṣe àfẹ́rí rẹ̀, Ọlọ́run Jakọbu. Sela.

7 Ẹ gbé orí yín sókè, háà! Ẹ̀yin ọ̀nà;
Kí á sì gbe yín sókè, ẹyin ìlẹ̀kùn ayérayé!
Kí ọba ògo le è wọlé.

8 Ta ni ọba ògo náà?
Olúwa tí ó lágbára tí ó sì le,
Olúwa gan an, tí ó lágbára ní ogun.

9 Gbé orí yín sókè, ẹyin ọ̀nà;
kí a sì gbé e yín sókè, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn ayérayé,
kí Ọba ògo le è wọlé wá.

10 Ta ni Ọba ògo náà?
Olúwa àwọn ọmọ-ogun
Òun ni Ọba ògo náà. Sela.

Filed Under: Featured

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Disclaimer: ( Please Read the Complete Disclaimer Then) All information/ material available on this website or the links handed on the point are for educational and instructional purposes only. We hold no responsibility for any profit, loss, or damage caused by or due to any information available on the point, either directly or laterally. The content is meant for individual and noncommercial uses only.
Copyright © 2023 · OMHBG

More

  • Biography Of Khaled Mahmoud (Age , Wife , Net Worth)
  • Biography of Minister Kalu Ugee Royaltee (Age , Husband)
  • 5 Ways To Identify A Scammer On Dating App
  • Governor Josh Green Phone Number & Contact
  • Best Web Design Company In Amodu
  • River Sing Me Home by Eleanor Shearer PDF
  • Comedy Whatsapp Group Names
  • Pastor Gabriel Olutola Prayer Request & Contact
  • Tamil Nadu Real Estate Whatsapp Group Link
  • Best Web Design Company In Dalemo
  • Best Web Design Company In Ogidi
  • Force of Faith - Kenneth Copeland (PDF)
  • Created Equal by Ben Carson | PDF
  • Healing Testimonies Andrew Wommack
  • Visualization Healing Stories
  • Cuba Whatsapp Group Links
  • 40 Best Prayer Points Against Lying Tongues
  • Berserk Deluxe Volume 13 by Kentaro Miura and Duane Johnson | PDF
  • Korean Yahoo Format
  • Top 10 Richest Men In Owo
  • Prophet Lovy Elias Itinerary 2023 - Register & Login
  • Pastor Chris Okotie Contact & Prayer Request
  • Biography of Apostle Lawal Suleiman (Age , Wife)
  • Biography of Minister Judikay (Age , Husband)
  • Healing Prayer For Chronic fatigue syndrome
  • Odumewu Debbie - Pinki Debbie
  • 527+ Bhakti Whatsapp Group Links
  • Where To Buy Jigsimur In Kogi State
  • Top 10 Richest Men In Ibadan
  • Giveaway Yahoo Format
  • Biography of Evangelist Lawrence Oyor (Age , Wife)
  • Speak To Your Mountain Joel Osteen PDF
  • Benin Yahoo Boy
  • Biography of Minister Bukola Bekes (Age , Husband)
  • Best Web Design Company In Arepo
  • Prophet Lovy Quotes (2023 List)
  • All the Dangerous Things by Stacy Willingham PDF
  • Betking Predictions WhatsApp Group Links
  • The Mystery Of The Blood - Apostle Joshua Selman (PDF)
  • 5265+ Telugu Whatsapp Group Links
  • 40 Prayer Points Against Unwanted Growth In The Body
  • In the Lives of Puppets by T.J. Klune PDF
  • Top 10 Richest Yahoo Boy In The World 2023
  • Kayanmata Spiritual Products
  • Best Web Design Company In Palmgrove
  • Un Voto: Haga Que su Voz Sea Escuchada [Make Your Voice Heard] by Ben Carson
  • 40 Prayer Points Against Hindrances To Breakthroughs
  • Yahoo Boy Format Book
  • Take and Receive Suscipe, Domine by St. Ignatius of Loyola
  • Gotv Customer Care Whatsapp Number Abuja